Ìròyìn Àwọn ènìyàn ti ṣèdájọ́ ní gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti Yúróòpù lòdì sí “Ìjọba Alákàsọ̀” tàbí “Ìjọba Àjẹ́pàtàkì” ti Trump.
Ìlera Dókítà ara Naijiria tó ń gbé ní Amẹ́ríkà sọ pé arákùnrin Ṣáínà ló fún un ní ìmísí láti dá gọ́gùùlù tó lè ṣàwárí àrùn cancer ṣẹ̀dá