Àkòrí: Ìdágìrì: Ǹjẹ́ owó ìrànwọ́ ilẹ̀ Amẹ́ríkà ń lọ sí apá fún Boko Haram?

Ẹ̀ka: Ìròyìn |

Aṣojú Scott Perry láti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti fi ẹ̀sùn kan àjọ USAID pé wọ́n ń lo owó ìlú láti ṣètìlẹ́yìn fún àwọn ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí bíi Boko Haram àti ISIS. Perry sọ pé owó tí ó tó mílíọ̀nù lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún dọ́là (over $600m) ni kò ní àkọsílẹ̀ tó múnádóko, tí ó sì ń bọ́ sí ọwọ́ àwọn tó ń dá rògbòdìyàn sílẹ̀ dípò kí ó lọ síbi iṣẹ́ ìrànwọ́ gidi.

Àwọn àsọyé

Ṣe ìbòwọ̀. Kò sí ọ̀rò ìkórìíra tàbí àkójọpọ̀ spam.

Kò sí àsọyé sibẹ̀.